Wed Jun 26 2019 11:25:26 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-06-26 11:25:28 +01:00
parent c3d9ff045a
commit 7e1624aa1b
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 36 Ẹnìkan sáré láti fí ọtí kíkan sí orí fùkẹ̀fùkẹ̀, wón fi sí orí ọ̀pá, wọ́n sì fun láti mu. Ọkùnrin náà wípé, "Ẹjẹ́ kí á wòó bóyá Elija yó wá múu sọ̀kalẹ̀." \v 37 Jésù sì kígbe lóhùn rara, ósì kú \v 38 Asọ ìkéle tẹ́mpílí sì fàya sí méjì láti òkè títí dé ìsàlẹ̀.
\v 36 Ẹnìkan sáré láti fí ọtí kíkan sí orí fùkẹ̀fùkẹ̀, wón fi sí orí ọ̀pá, wọ́n sì fi fun láti mu. Ọkùnrin náà wípé, "Ẹjẹ́ kí á wòó bóyá Èlíjà yó wá múu sọ̀kalẹ̀." \v 37 Jésù sì kígbe lóhùn rara, ósì kú \v 38 Asọ ìkéle tẹ́mpílí sì fàya sí méjì láti òkè títí dé ìsàlẹ̀.