Tue May 18 2021 20:38:42 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
aanuoluwapoadegoke 2021-05-18 20:38:43 +01:00
parent 092dc134f0
commit 7d7794bcd0
3 changed files with 4 additions and 2 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 13 Ó sì wí fún wọn pé, “Sé òwe yìí kò yé e yín ni? Báwo ni ẹ̀yin yóò ṣe mọ ìtumọ̀ àwọn òwẹ mìíràn? \v 14 Afúnrúgbìn tí ó ǹ fúnrúgbìn ni ó ń fúnrúgbìn ọ̀rọ̀ náà. \v 15 Èyí ǐ ni àwọn tó bọ́ sí ojú ọ̀nà, níbi tí a fúnrúgbìn ọ̀rọ̀ sí, ṣùgbọ́n nígbà tí wọ́n gbọ́ ọ̀rọ̀ náà, lójúkan náà èṣù wá ó sì mú ohun tí wọ́n ti
\v 13 Ó sì wí fún wọn pé, “Sé òwe yìí kò yé e yín ni? Báwo ni ẹ̀yin yóò ṣe mọ ìtumọ̀ àwọn òwẹ mìíràn? \v 14 Afúnrúgbìn tí ó ǹ fúnrúgbìn ni ó ń fúnrúgbìn ọ̀rọ̀ náà. \v 15 Èyí ǐ ni àwọn tó bọ́ sí ojú ọ̀nà, níbi tí a fúnrúgbìn ọ̀rọ̀ sí, ṣùgbọ́n nígbà tí wọ́n gbọ́ ọ̀rọ̀ náà, lójúkan náà èṣù wá ó sì mú ohun tí wọ́n ti gbìn kúrò.

1
04/16.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 16 Èyí ni àwọn tí ó bọ́ sórí àpáta, nígbà tí wọ́n bá gbọ́ ọrọ̀ náà, ló wọ́n fi ayọ̀ gbọ́ ọ̀rọ̀ Ọlọ́run. 17Ṣùgbọ́n kò ni gbòǹgbò tí ó jinlẹ̀ ní ọkàn wọn. Ṣùgbọ́n wọ́n á wà fún ìgbà díẹ̀, lẹ́yìn náà nígbà ti wàhálà tàbí inúnibíni bá dìde nítorí ọ̀rọ̀ náà, lójúkan náà, wọ́n á kọsẹ̀. \v 17 dd

View File

@ -61,6 +61,7 @@
"04-03",
"04-06",
"04-08",
"04-10"
"04-10",
"04-13"
]
}