Fri Nov 08 2019 21:47:47 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
EDUNOLAOLUWA 2019-11-08 21:47:47 +01:00
parent e5c6f9fd85
commit 7903772531
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 26 Bó tilẹ̀ jẹ́ wípé èyí ba ọba nínú jẹ́, kò le sa láì mú ìbéèrè rẹ̀ se nítorí tí óti búra fún un àti nítorí àwọn àlejò rẹ̀. \v 27 Ọba rán awon emewa re ki won lo be ori Johanu wa. Emewa naa si lo be ori Johanu lati inu ogba ewon wa \v 28 Osi gbe fun odomobirin naa ninu igba, omobirin naa si lo gbe fun iya re. \v 29 Nigbati awon omoleyin re gbo, won lo gbe ara re toku lo si iboji.
\v 26 Bó tilẹ̀ jẹ́ wípé èyí ba ọba nínú jẹ́, kò le sa láì mú ìbéèrè rẹ̀ se nítorí tí óti búra fún un àti nítorí àwọn àlejò rẹ̀. \v 27 Ọba rán àwọn emèwà rẹ̀ kí wọ́n lọ bẹ́ orí Jòhánù wá. Ẹmẹ̀wà náà si lo be ori Johanu lati inu ogba ewon wa \v 28 Osi gbe fun odomobirin naa ninu igba, omobirin naa si lo gbe fun iya re. \v 29 Nigbati awon omoleyin re gbo, won lo gbe ara re toku lo si iboji.