Thu May 16 2019 12:43:34 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-05-16 12:43:35 +01:00
parent 813663d0ce
commit 765b778456
2 changed files with 2 additions and 2 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 28 Nígbàtí Jésù sì wọlé wá, àwọn ọmọ ẹ̀hìn rẹ bií ní ìkọ̀kọ̀ pé, "Èése tí àwa kò fi le è lèe jáde." \v 29 Ó dáhùn ós´ wí fún won pé, "Irú èyí kòle séése bíkòse nípasẹ̀ àdúrá."
\v 28 Nígbàtí Jésù sì wọlé wá, àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ bií ní ìkọ̀kọ̀ pé, "Èéṣe tí àwa kò fi le è lèe jáde." \v 29 Ó dáhùn ósì wí fún won pé, "Irú èyí kò le ṣééṣe bíkòṣe nípasẹ̀ àdúrá."

View File

@ -1 +1 @@
\v 30 Wọ́n sì jáde lọ kúrò níbè, wọ́n gba agbègbè Gálílì lọ. Jésù kò fé kí ẹnìkankan kí ó mọ ibi tí àwọn wà, \v 31 nítorí tí Ó n kọ́ àwọn ọmọ ẹ̀hìn Rẹ̀. Ó sọ fún wọn wípé, "A ó fi Ọmọ Ènìyàn lé àwọn ènìyàn lọ́wọ́, wọn ó sì se ikú paá. Lẹ́yìn ìgbà tí ó bá kú tán, lẹ́hìn ọjọ́ kẹta yíò jí dìde , \v 32 Sùgbọ́n ọ̀rọ̀ tí ó n sọ yìí kò yéwọn, ẹ̀rù si n bàwọ́n láti bèèrè lọ́wọ́ Rẹ̀.
\v 30 Wọ́n sì jáde lọ kúrò níbẹ̀, wọ́n gba agbègbè Gálílì lọ. Jésù kò fé kí ẹnìkankan kí ó mọ ibi tí àwọn wà, \v 31 nítorí tí Ó n kọ́ àwọn ọmọ ẹ̀hìn Rẹ̀. Ó sọ fún wọn wípé, "A ó fi Ọmọ Ènìyàn lé àwọn ènìyàn lọ́wọ́, wọn ó sì se ikú paá. Lẹ́yìn ìgbà tí ó bá kú tán, lẹ́hìn ọjọ́ kẹta yíò jí dìde , \v 32 Sùgbọ́n ọ̀rọ̀ tí ó n sọ yìí kò yéwọn, ẹ̀rù si n bàwọ́n láti bèèrè lọ́wọ́ Rẹ̀.