diff --git a/08/31.txt b/08/31.txt index 4a31196..bb07a49 100644 --- a/08/31.txt +++ b/08/31.txt @@ -1 +1 @@ -\v 31 Ó sì bẹ̀rẹ̀ sí kọ́ wọn pé, Ọmọ Ènìyàn kò le ṣàìmá jìyà ohun púpọ̀, a ó sì kọ̀ ọ́ sílẹ̀ láti ọwọ́ àwọn àgbàgbà, àwọn olórí àlùfáà àti àwọn olùkọ́ òfin, a ó sì pa á, lẹ́yìn ọjọ́ mẹ́ta yóò sì jíǹde. \v 32 Ó sọ èyí láìfi ohunkóhun pamọ́ fún wọn, ṣùgbọ́n Peteru pe Jesu sẹ́yìn, ó sì bẹ̀rẹ̀ si bá a wí. \ No newline at end of file +\v 31 Ó sì bẹ̀rẹ̀ sí kọ́ wọn pé, Ọmọ Ènìyàn kò le ṣàìmá jìyà ohun púpọ̀, a ó sì kọ̀ ọ́ sílẹ̀ láti ọwọ́ àwọn àgbàgbà, àwọn olórí àlùfáà àti àwọn olùkọ́ òfin, a ó sì pa á, lẹ́yìn ọjọ́ mẹ́ta yóò sì jíǹde. \v 32 Ó sọ èyí láìfi ohunkóhun pamọ́ fún wọn. Peteru pe Jesu sẹ́yìn, ó sì bẹ̀rẹ̀ si bá a wí. \ No newline at end of file diff --git a/08/33.txt b/08/33.txt new file mode 100644 index 0000000..7195440 --- /dev/null +++ b/08/33.txt @@ -0,0 +1,3 @@ +\v 33 Ṣùgbọ́n Jesu yípadà, ó wo àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀. Ó sì dá Peteru lẹ́kun, “Kúrò lẹ́yìn mi, Satani! Iwọ kò ro ohun tí Ọlọ́run bí kò ṣe ohun tí ènìyàn.” +Ọ̀nà sí àgbélébùú +34 Nígbà náà ni Jesu pe àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ àti ọ̀pọ̀ ènìyàn láti bá wọn sọ̀rọ̀, ó wí fún wọn pé, “Bí ẹnikẹ́ni bá fẹ́ tọ̀ mí lẹ́yìn, kí ó sẹ́ ara rẹ̀, kí ó si gbé àgbélébùú rẹ̀, kí ó si máa tọ̀ mi lẹ́yìn.\v 34 dd \ No newline at end of file diff --git a/manifest.json b/manifest.json index 020cb7c..53c2faa 100644 --- a/manifest.json +++ b/manifest.json @@ -85,6 +85,7 @@ "08-22", "08-24", "08-27", - "08-29" + "08-29", + "08-31" ] } \ No newline at end of file