diff --git a/05/21.txt b/05/21.txt index 568c392..8a219d8 100644 --- a/05/21.txt +++ b/05/21.txt @@ -1 +1 @@ -\v 22 \v 23 \v 24 \v 21 Nigbati Jesu ti re koja si odi keji, ninu ọkọ oju omi, ọpọlọpọ eniyan yi ka, bi o ti wa legbe okun. O kan ninu awon aladari sinagọgue, eni ti oruko re je Jairu, o waa, nigbati o si ri, o dọbale niwaju rẹ.\v 22 O bẹ, o si tun bẹ wipe, Omo mi obinrin kekere fẹrẹ ku. Mo bẹ Ọ, wa da ọwọ rẹ le ki o le pada bo si po ki o si wa ni alafia. O si ba lo. ọpọlọpọ eniyan si ba lọ ati pe wọn sumọ pẹkipẹki ni agbegbe naa. \ No newline at end of file +\v 21 Nigbati Jesu ti re koja si odi keji, ninu ọkọ oju omi, ọpọlọpọ eniyan yi ka, bi o ti wa legbe okun. \v 22 O kan ninu awon aladari sinagọgue, eni ti oruko re je Jairu, o waa, nigbati o si ri, o dọbale niwaju rẹ. \v 23 O bẹ, o si tun bẹ wipe, Omo mi obinrin kekere fẹrẹ ku. Mo bẹ Ọ, wa da ọwọ rẹ le ki o le pada bo si po ki o si wa ni alafia. \v 24 Nitorina o ba lo. ọpọlọpọ eniyan si ba lọ ati pe wọn sumọ pẹkipẹki ni agbegbe naa. \ No newline at end of file