Mon May 13 2019 10:08:15 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-05-13 10:08:16 +01:00
parent 8311f103fe
commit 6d6dab9cfa
2 changed files with 2 additions and 2 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 16 \v 15 Jesu si nje ounje ninu ile Lefi ati opolopo awon agbowo ode ati awon eniyan elese won ba a jeun pelu awon omo eyin re, opolopo si wa nibe won si nto lehin.\v 16 Nigbati awon akowe, ti won je Farisi, ri ti Jesu njeun pelu awon eniyan elese ati awon agbowo ode, won wi fun awon omo eyin re pe, "Kilo sele ti O nfi ba awon agbowo ode ati eniyan elese jeun"
\v 15 Jesu si nje ounje ninu ile Lefi ati opolopo awon agbowo ode ati awon eniyan elese won ba a jeun pelu awon omo eyin re, opolopo si wa nibe won si nto lehin. \v 16 Nigbati awon akowe, ti won je Farisi, ri ti Jesu njeun pelu awon eniyan elese ati awon agbowo ode, won wi fun awon omo eyin re pe, "Kilo sele ti O nfi ba awon agbowo ode ati eniyan elese jeun"

View File

@ -1 +1 @@
\v 17 Nigbati Jesu gbo oro yi O wi fun won pe, "Awon eniyan ti ara won ya ki wa onisegun; awon ti ara won ko ya ni"
\v 17 Nigbati Jesu gbo oro yi O wi fun won pe, "Awon eniyan ti ara won ya ki wa onisegun; awon ti ara won ko ya ni won nilo re. Emi ko wa lati pe awon olododo bikose awon eniyan elese."