Fri May 17 2019 21:20:14 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-05-17 21:20:15 +01:00
parent f9e549b05f
commit 68c4ddcde8
3 changed files with 3 additions and 3 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 5 Ó sí wò yí ká pẹ̀lú ìbínú, àti pé inú rẹ bàjẹ́ nítorí àyà líle wọn, ó sì wí fun okùnrin náà pé, "Na ọwọ́ rẹ jade." Ó sì na ọwọ́ rẹ jáde, ó sí bọ̀ sípò. \v 6 Àwọn Farisí sì jáde lojukan naa wọn si bẹ̀rẹ̀ si gbìmọ̀ pọ̀ pẹ̀lú àwọn Olùtẹ̀lé Hẹ́ródù bí wọn ó se pa Jésù.
\v 5 Ó sí wò yí ká pẹ̀lú ìbínú, àti pé inú rẹ bàjẹ́ nítorí àyà líle wọn, ó sì wí fun okùnrin náà pé, "Na ọwọ́ rẹ jade." Ó sì na ọwọ́ rẹ jáde, ó sí bọ̀ sípò. \v 6 Àwọn Farisí sì jáde lojukan nàà wọn si bẹ̀rẹ̀ si gbìmọ̀ pọ̀ pẹ̀lú àwọn Olùtẹ̀lé Hẹ́ródù bí wọn ó se pa Jésù.

View File

@ -1 +1 @@
\v 7 Lẹ́yìn naa Jésù pẹ̀lú àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ sì lọ sí ojó odò Gálílì, ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ènìyàn sí tèlé wọn lati Gálílì ati lati Judia. \v 8 Lati Jerusalemu ati lati ilẹ̀ àwọn ará Édómù ati lati ẹ̀yìn odò Jódánì wa ati àgbègbè àwọn ará Tireni oun Sidoni wa. Ńigbá tí wọ́n sí gbọ́ àwọn ohun àrà tí à ń ti ọ́wọ rẹ̀ se ọ̀pọ́ àwọn ènìyàn tọọ wa.
\v 7 Lẹ́yìn naa Jésù pẹ̀lú àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ sì lọ sí odò Gálílì, ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ènìyàn sí tèlé wọn lati Gálílì ati lati Judia. \v 8 Lati Jerusalemu ati lati ilẹ̀ àwọn ará Édómù ati lati ẹ̀yìn odò Jódánì wa ati àgbègbè àwọn ará Tireni oun Sidoni wa. Ńigbá tí wọ́n sí gbọ́ àwọn ohun àrà tí à ń ti ọ́wọ rẹ̀ se ọ̀pọ́ àwọn ènìyàn tọọ wa.

View File

@ -39,7 +39,7 @@
"03-title",
"03-01",
"03-03",
"03-07",
"03-05",
"03-09",
"03-11",
"03-13",