Tue May 18 2021 11:50:47 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
aanuoluwapoadegoke 2021-05-18 11:50:48 +01:00
parent e64e7a376a
commit 68539eb30c
3 changed files with 4 additions and 3 deletions

View File

@ -1,2 +1 @@
\v 32 Ní àṣálẹ́, tí oòrùn ti wọ̀, wọ́n gbé gbogbo àwọn aláìsàn àti àwọn tó ni ẹ̀mí àìmọ́ tọ̀ ọ́ wá. \v 33 Gbogbo ìlú si péjọ ni ẹnu-ọ̀nà. \v 34 Ó sì wo ọ̀pọ̀ tí wọ́n ní onírúurú ààrùn sàn. Bákan náà ni ó lé ọ̀pọ̀ ẹ̀mí àìmọ́ jáde, Ṣùgbọ́n kò sì jẹ́ kí àwọn ẹ̀mí àìmọ́ náà kí ó sọ̀rọ̀, nítorí tí wọ́n mọ ẹni tí òun í ṣe. \v 32 Ní àṣálẹ́, tí oòrùn ti wọ̀, wọ́n gbé gbogbo àwọn aláìsàn àti àwọn tó ni ẹ̀mí àìmọ́ tọ̀ ọ́ wá. \v 33 Gbogbo ìlú si péjọ ni ẹnu-ọ̀nà. \v 34 Ó sì wo ọ̀pọ̀ tí ó ní onírúurú ààrùn sàn, ó sì tún lé ọ̀pọ̀ ẹ̀mí àìmọ́ jáde, ṣùgbọ́n kò jẹ́ kí àwọn ẹ̀mí àìmọ́ náà sọ̀rọ̀ nítorí tí wọ́n mọ̀ ọ́.
Jesu ya ara rẹ̀ sọ́tọ̀ láti gbàdúrà

1
01/35.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 35 \v 36 \v 37 cc

View File

@ -49,6 +49,7 @@
"01-21", "01-21",
"01-23", "01-23",
"01-27", "01-27",
"01-29" "01-29",
"01-32"
] ]
} }