From 64b8c0ff568511e88b8dd66ee397dcbc5d15e2d1 Mon Sep 17 00:00:00 2001 From: aanuoluwapoadegoke Date: Tue, 18 May 2021 21:40:39 +0100 Subject: [PATCH] Tue May 18 2021 21:40:39 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time) --- 04/35.txt | 2 +- 1 file changed, 1 insertion(+), 1 deletion(-) diff --git a/04/35.txt b/04/35.txt index 3e25f1a..9ce028a 100644 --- a/04/35.txt +++ b/04/35.txt @@ -1 +1 @@ -\v 35 Ní ọjọ́ náà, nígbà tí alẹ́ lẹ́, ó wí fún wọn pé, “Ẹ jẹ́ kí a rékọjá sí apá kejì.” 36Nígbà tí wọn ti tú ìjọ ká, wọ́n sì gbà á sínú ọkọ̀ ojú omi gẹ́gẹ́ bí ó ti wà. Àwọn ọkọ̀ ojú omi kékeré mìíràn sì wà lọ́dọ̀ rẹ̀. 37Ìjì líle ńlá kan sì dìde, omi sì ń bù sínú ọkọ̀, tó bẹ́ẹ̀ tí ọkọ̀ fi bẹ̀rẹ̀ sí í kún fún omi, ó sì fẹ́rẹ rì. \v 36 \v 37 ss \ No newline at end of file +\v 35 Ní ọjọ́ náà, nígbà tí alẹ́ lẹ́, ó wí fún wọn pé, “Ẹ jẹ́ kí a rékọjá sí apá kejì.” 37Ìjì líle ńlá kan sì dìde, omi sì ń bù sínú ọkọ̀, tó bẹ́ẹ̀ tí ọkọ̀ fi bẹ̀rẹ̀ sí í kún fún omi, ó sì fẹ́rẹ rì. \v 36 Wọ́n fi ọpọ̀ erò sílẹ̀, wọ́n mú Jésù pẹ̀lú wọn, gẹ́gé bí ó ti wà nínú ọkọ̀ ojú omi gẹ́gẹ́ bí ó ti wà. Àwọn ọkọ̀ ojú omi kékeré mìíràn sì wà lọ́dọ̀ rẹ̀. \v 37 ss \ No newline at end of file