Thu May 20 2021 14:18:13 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)
This commit is contained in:
parent
aaab452b54
commit
640c4ac56c
|
@ -1 +1 @@
|
|||
\c 12 \v 1 Nígbà náà ni Jésù bẹ̀rẹ̀ sí í fi òwe kọ́ wọn. Ó wípe, “Ọkùnrin kan gbin ọgbà àjàrà kan, Ó ṣe ọgbà yìí ká, ó sì wá ilẹ̀ fún ìfúntí wáìnì. Ó kọ́ ilé ìṣọ́, ó sì fi ṣe àgbàtọ́jú fún àwọn olùṣọ́gbà. Ó sì lọ sí ìrìnàjò. \v 2 Lákokò tí ó tọ́, ọkùnrin náà rán ọ̀kan nínú àwọn ọmọ ọ̀dọ̀ rẹ̀ sí àwọn olùṣọ́gbà náà, kí ó gbà nínú èso ọgbà àjàrà náà lọ́wọ́ àwọn olùṣọ́gbà. \v 3 Ṣùgbọ́n àwọn àgbẹ̀ wọ̀n-ọn-nì lu ìránṣẹ́ ọkùnrin náà, wọ́n sì rán an padà lọ́wọ́ òfo.
|
||||
\c 12 \v 1 Nígbà náà ni Jésù bẹ̀rẹ̀ sí í fi òwe kọ́ wọn. Ó wípe, “Ọkùnrin kan gbin ọgbà àjàrà kan, Ó ṣe ọgbà yìí ká, ó sì wá ilẹ̀ fún ìfúntí wáìnì. Ó kọ́ ilé ìṣọ́, ó sì fi ṣe àgbàtọ́jú fún àwọn olùṣọ́gbà. Ó sì lọ sí ìrìnàjò. \v 2 Lákokò tí ó tọ́, ọkùnrin náà rán ọ̀kan nínú àwọn ọmọ ọ̀dọ̀ rẹ̀ sí àwọn olùṣọ́gbà náà, kí ó gbà nínú èso ọgbà àjàrà náà lọ́wọ́ àwọn olùṣọ́gbà. \v 3 Ṣùgbọ́n wọ́n mú u, wọ̀n lù ú, wọ́n sì rán an padà lọ́wọ́ òfo.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 4 Ó sì tún rán ọmọ ọ̀dọ̀ mìíràn sí wọn, ṣùgbọ́n wọ́n dá ọgbẹ́ sí i lórí, wọn rán an lọ ni ìtìjú. 5Ó sì tún rán òmíràn, èyí n nì wọ́n sì pa, àti ọ̀pọ̀ mìíràn, wọ́n lu òmíràn wọ́n sì pa òmíràn. \v 5 dd
|
|
@ -90,6 +90,7 @@
|
|||
"08-33",
|
||||
"08-35",
|
||||
"08-38",
|
||||
"12-title"
|
||||
"12-title",
|
||||
"12-01"
|
||||
]
|
||||
}
|
Loading…
Reference in New Issue