Tue May 14 2019 16:10:08 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-05-14 16:10:10 +01:00
parent 7db95b1300
commit 608567e783
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 2 Wọ́n ríi wípé àwọn kan nínú àwọn ọmọẹ̀yìn Rẹ̀ ń jẹhun pẹ̀lú ọwọ́ àìmọ́, eyí ni, láì fọwọ́ . \v 3 (Nítorípé àwọn Farisí àti gbogbo àwọn Júù kìí jẹhun láì jẹ́ pé wọ́n bá fọwọ́, nítorípé wọ́n fi ọwọ́ gidi mú àsá àwọn àgbààgbà. \v 4 Tí àwọn Farisí bá ti ọjà dé, wọn kìí jẹhun bíkòsepé wọ́n bá kọ́kọ́ wẹ ara wọn, bẹ́ẹ̀ni wọ́n sì di àwọn àsà míràn náà mú sinsin, bíi fífọ ife ìmumi, ìkòkò, ohun èlò amọ̀n, àti àwọn tábìlì tí wọ́n bá fi jẹhun.)
\v 2 Wọ́n ríi wípé àwọn kan nínú àwọn ọmọẹ̀yìn Rẹ̀ ń jẹhun pẹ̀lú ọwọ́ àìmọ́, eyí ni, láì fọwọ́ . \v 3 (Nítorípé àwọn Farisí àti gbogbo àwọn Júù kìí jẹhun láì jẹ́ pé wọ́n bá fọwọ́, nítorípé wọ́n fi ọwọ́ gidi mú àsá àwọn àgbààgbà. \v 4 Tí àwọn Farisí bá ti ọjà dé, wọn kìí jẹhun bíkòsepé wọ́n bá kọ́kọ́ wẹ ara wọn, bẹ́ẹ̀ni wọ́n sì di àwọn àsà míràn náà mú sinsin, bíi fífọ ife ìmumi, ìkòkò, ohun èlò idẹ, àti àwọn tábìlì tí wọ́n bá fi jẹhun.)