Fri May 17 2019 08:45:20 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-05-17 08:45:20 +01:00
parent 7dd171db53
commit 5e617889f8
3 changed files with 3 additions and 3 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 30 Nítòótó, mo sọ fún un yín, ìran yí kò ní kọjá lọ títí gbogbo ǹkan wọ̀nyi yóò fi wá sí ìmúṣẹ. \v 31 Ọ̀run àti ayé yíò kọjá lọ, ṣùgbọ́n àwọn ọ̀rọ̀ mi kì yóò kọjá. \v 32 Ṣùgbọ́n nípa ọjọ́ náà tàbí wákàtí náà, ẹ́nìkan kò mọ̀, kódà àwọn ángélì, tàbí Ọmọ, bíkòṣe Baba nìkan mọ̀.
\v 30 Nítòótó, mo sọ fún un yín, ìran yí kò ní kọjá lọ títí gbogbo ǹkan wọ̀nyi yóò fi wá sí ìmúṣẹ. \v 31 Ọ̀run àti ayé yíò kọjá lọ, ṣùgbọ́n àwọn ọ̀rọ̀ mi kì yóò kọjá. \v 32 Ṣùgbọ́n nípa ọjọ́ náà tàbí wákàtí náà, ẹ́nìkan kò mọ̀, kódà àwọn ángélì, tàbí Ọmọ, bíkòṣe Baba nìkan ní ò mọ̀.

View File

@ -1 +1 @@
\v 33 Ẹ kíyèsára! Ẹ ṣọ́nà, nítorí ẹ kò mọ àkokò tí yíò jẹ̀ ẹ́. \v 34 Ó dàbí okùnrin kan tí ó lọ ìrìnàjò- ó fi ilé rẹ̀ sílẹ̀, o si fi ọmọọ̀dọ̀ rẹ̀ ṣi àbojútó ilé rẹ̀, enikọ̀ọ̀kan pẹ̀lú iṣẹ́ rẹ̀, o si pàṣẹ fún aṣọ́nà kí ó ma sùn.
\v 33 Ẹ kíyèsára! Ẹ ṣọ́nà, nítorí ẹ kò mọ àkokò tí yíò jẹ̀ ẹ́. \v 34 Ó dàbí ọkùnrin kan tí ó n lọ sí ìrìnàjò- ó fi ilé rẹ̀ sílẹ̀, o si fi ọmọọ̀dọ̀ rẹ̀ ṣe àbojútó ilé rẹ̀, enikọ̀ọ̀kan pẹ̀lú iṣẹ́ rẹ̀, o si pàṣẹ fún aṣọ́nà kí ó ma sùn.

View File

@ -47,7 +47,7 @@
"13-21",
"13-24",
"13-28",
"13-33",
"13-30",
"13-35"
]
}