Thu May 20 2021 13:36:12 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
aanuoluwapoadegoke 2021-05-20 13:36:13 +01:00
parent fa5ad6ebb1
commit 5e3dc97272
1 changed files with 1 additions and 3 deletions

View File

@ -1,3 +1 @@
\v 27 Jesu àti àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ kúrò ní Galili. Wọ́n sì jáde lọ sí àwọn abúlé ní agbègbè Kesarea-Filipi. Bí wọ́n ti ń lọ lọ́nà, ó béèrè lọ́wọ́ wọn pé, “Ta ni àwọn ènìyàn ń fi mí pè?”
28 Àwọn ọmọ-ẹ̀yìn náà dáhùn pé, “Àwọn kan rò pé ìwọ ni Johanu Onítẹ̀bọmi, àwọn mìíràn sọ pé, ìwọ ni Elijah tàbí àwọn wòlíì mìíràn ni ó tún padà wá sáyé.”
\v 28 ss
\v 27 Jesu àti àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ jáde lọ sí àwọn abúlé ní agbègbè Kesaréà Fílípì. Lójú ọnà, ó bi àwọn ọmọ ẹyìn rẹ̀ pé, “Ta ni àwọn ènìyàn ń fi mí pè?” \v 28 Wọ́n dáhùn pé, “Johanu Onítẹ̀bọmi, àwọn mìíràn sọ pé, ìwọ ni Elijah tàbí àwọn wòlíì mìíràn ni ó tún padà wá sáyé.”