Thu May 20 2021 14:32:13 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
aanuoluwapoadegoke 2021-05-20 14:32:13 +01:00
parent 77b19c702d
commit 5d2951af25
3 changed files with 5 additions and 2 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 10 Tàbí ẹ̀yin kò ì tí ka ẹsẹ yìí nínú ìwé mímọ́? Òkúta tí àwọn ọ̀mọ̀lé kọ̀sílẹ̀, òun náà ni ó di pàtàkì igun ilé. \v 11 Èyí wá láti ọdọ̀ Olúwa, ó sì jẹ́ ìyàlẹ́nu lójú tiwa?” \v 12 Wọ́n ń wá ọnà láti mú Jesu, Nítorí tí wọ́n mọ̀ pé àwọn ló ń pòwe mọ́ nínú ọ̀rọ̀ rẹ̀. Àwọn ni alágbàtọ́jú búburú nínú ìtàn rẹ̀. Ṣùgbọ́n ẹ̀rù ń bà wọ́n láti fọwọ́ kàn án nítorí pé wọ́n bẹ̀rù ìhùwàsí ọ̀pọ̀ ènìyàn tó wà lọ́dọ̀ rẹ̀. Nítorí náà wọ́n fi í sílẹ̀ lọ.
\v 10 Tàbí ẹ̀yin kò ì tí ka ẹsẹ yìí nínú ìwé mímọ́? Òkúta tí àwọn ọ̀mọ̀lé kọ̀sílẹ̀, òun náà ni ó di pàtàkì igun ilé. \v 11 Èyí wá láti ọdọ̀ Olúwa, ó sì jẹ́ ìyàlẹ́nu lójú tiwa?” \v 12 Wọ́n ń wá ọnà láti mú Jesu, ṣùgbọ́n ẹ̀rù ń bà wọ́n nítorí ọ̀pọ̀ ènìyàn tó wà lọ́dọ̀ rẹ̀, nítorí tí wọ́n mọ̀ pé àwọn ló ń pòwe mọ́. Nítorí náà wọ́n fi í sílẹ̀ lọ.

2
12/13.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1,2 @@
\v 13 Ṣùgbọ́n wọ́n rán àwọn Farisi pẹ̀lú àwọn kan tí í ṣe ọmọ-ẹ̀yìn Herodu wá sọ́dọ̀ Jesu, láti fi ọ̀rọ̀ wá a lẹ́nu wò, títí yóò fi sọ ohun kan kí wọn lè rí fi mú. 14Bí wọn ti dé ọ̀dọ̀ rẹ̀, wọ́n wí pé: “Olùkọ́, àwa mọ̀ pé ìwọ máa ń sọ òtítọ́ láìsí ìbẹ̀rù ẹnikẹ́ni. Ṣùgbọ́n òtítọ́ ọ̀rọ̀ Ọlọ́run ni ìwọ máa ń kọ́ni. Nísinsin yìí, sọ fún wa, ó tọ́ tàbí kò tọ́ láti máa san owó orí fún Kesari?” 15Kí àwa kí ó fi fún un, tàbí kí a máa fi fún un?
Ṣùgbọ́n Jesu mọ ìwà àgàbàgebè wọn. Ó sì wí pé, “Èéṣe tí ẹ̀yin fi n fi èyí dán mi wo? Ẹ mú owó idẹ kan wá kí n wò ó.”\v 14 \v 15 dd

View File

@ -94,6 +94,7 @@
"12-01",
"12-04",
"12-06",
"12-08"
"12-08",
"12-10"
]
}