Fri Nov 08 2019 20:05:46 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)
This commit is contained in:
parent
97b83cbe03
commit
55d507b684
|
@ -1 +1 @@
|
|||
\c 6 \v 1 Ó sì jáde lọ sí ìlú abínibí rẹ̀, àwọn ọmọ ẹ̀yin rẹ̀ sì tẹ̀ le. \v 2 Nígbàtí ódi ọjọ́ Ìsinmi, Ó nkọ́ wọn nínú sínágógù. Òpò ènìyàn sì gbọ́ ẹ̀kọ́ náà, ẹnú sì yà wọ́n. Won si bere wipe, "nibo ni o ti ri gbogbo eko ti on ko ni yi?" "Iru ogbon wo ni afi fun yi?" "Iru awon ise iyanu wo ni on fi owo re se wonyi?" \v 3 "Se kii se gbenagbena naa ni yi, omo bibi Maria, ati arakunrin Jemisi, ati Jose, ati Juda, ati Simoni? Sebi awon arabirin re ngbe pelu wa?" Inu Jesu si bi won.
|
||||
\c 6 \v 1 Ó sì jáde lọ sí ìlú abínibí rẹ̀, àwọn ọmọ ẹ̀yin rẹ̀ sì tẹ̀ le. \v 2 Nígbàtí ódi ọjọ́ Ìsinmi, Ó nkọ́ wọn nínú sínágógù. Òpò ènìyàn sì gbọ́ ẹ̀kọ́ náà, ẹnú sì yà wọ́n. Wọ́n sì bèèrè wípé, "níbo ni o ti rí gbogbo ẹ̀kọ́ tí ò ń kọ́ ni yí?" "Irú ọgbọ́n wo ni afi fun yi?" "Iru awon ise iyanu wo ni on fi owo re se wonyi?" \v 3 "Se kii se gbenagbena naa ni yi, omo bibi Maria, ati arakunrin Jemisi, ati Jose, ati Juda, ati Simoni? Sebi awon arabirin re ngbe pelu wa?" Inu Jesu si bi won.
|
Loading…
Reference in New Issue