diff --git a/06/18.txt b/06/18.txt index af69c88..ead8c31 100644 --- a/06/18.txt +++ b/06/18.txt @@ -1 +1 @@ -\v 18 Nitori Johanu ba Herodu wi nitori iyawo arakunrin re ti o yan lale. \v 19Herodia si binu si Johanu, o si n wa ona lati pa a, eyi nira fun nitori Herodu beru Johanu. Ati wipe o mo pe olotito ati eniyan mimo ni. Oro lati enu Johanu ma n bii ninu, sugbon o ma n fi ayo gboo. \ No newline at end of file +\v 18 Nitori Johanu ba Herodu wi, "pe ko tona lati yan aya arakunrin re lale." \v 19 Herodia si binu si Johanu, o si n wa ona lati pa a, eyi nira fun \v 20 nitori Herodu beru Johanu. Ati wipe o mo pe olotito ati eniyan mimo ni. Oro lati enu Johanu ma n bii ninu, sugbon o ma n fi ayo gboo. \ No newline at end of file