Tue May 18 2021 11:38:47 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
aanuoluwapoadegoke 2021-05-18 11:38:48 +01:00
parent b5c81e4bcc
commit 50fdefa764
3 changed files with 6 additions and 3 deletions

View File

@ -1,2 +1 @@
\v 23 Nígbà náà ọkùnrin kan tí ó wà nínú Sinagọgu wọn, tí ó ní ẹ̀mí àìmọ́ bẹ̀rẹ̀ sí í kígbe,
\v 24 wí pé, “Kí ni àwa ní se pèlu rẹ, Jésù ti Násárẹ́tì? Ṣé ìwọ wá láti pa wá run ni? Èmí mọ ẹni tí ìwọ í ṣe; Ìwọ ní ẹni Mímọ́ Ọlọ́run!” \v 25 Jesu si bá èmí èsù náà wí, ó wí pé, “Pa ẹnu rẹ mọ́, kí ó sì jáde kúrò lára rẹ̀!.” \v 26 ss
\v 23 Nígbà náà ọkùnrin kan tí ó wà nínú Sinagọgu wọn, tí ó ní ẹ̀mí àìmọ́ bẹ̀rẹ̀ sí í kígbe, \v 24 wí pé, “Kí ni àwa ní se pèlu rẹ, Jésù ti Násárẹ́tì? Ṣé ìwọ wá láti pa wá run ni? Èmí mọ ẹni tí ìwọ í ṣe; Ìwọ ní ẹni Mímọ́ Ọlọ́run!” \v 25 Jesu si bá èmí èsù náà wí, ó wí pé, “Pa ẹnu rẹ mọ́, kí ó sì jáde kúrò lára rẹ̀!.” \v 26 Ẹ̀mí àìmọ́ náà sì gbé e sánlè, ó sì jáde kúrò lára ọkùnrin náà bí ó ti ń ké ní ohùn rara,.

3
01/27.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1,3 @@
\v 27 Ẹnu sì ya àwọn ènìyàn, tó bẹ́ẹ̀ tí wọ́n fi ń sọ láàrín ara wọn ohun tí ó ti ṣẹlẹ̀. Wọ́n béèrè pẹ̀lú ìgbóná ara, pé, “Kí ni èyí? Irú ẹ̀kọ́ tuntun wo ni èyí? Ó ń fi agbára pàṣẹ fún àwọn ẹ̀mí àìmọ́ pàápàá wọ́n sì gbọ́ tirẹ̀.” 28Ìròyìn nípa rẹ̀ tàn ká gbogbo agbègbè Galili.
Jesu mú ọ̀pọ̀ ènìyàn láradá
\v 28 dd

View File

@ -46,6 +46,7 @@
"01-14",
"01-16",
"01-19",
"01-21"
"01-21",
"01-23"
]
}