Wed Jun 26 2019 09:47:26 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)
This commit is contained in:
parent
f59aeb7228
commit
4ff666116e
|
@ -1 +1 @@
|
|||
\c 15 \v 1 Ní àárọ̀ kùtùkùtù, àwọn olórí àlúfàà pàdé pẹ̀lú àwọn àgbààgbà pẹ̀lú àwọn akọ̀wé àti gbogbo ìgbìmọ̀ àwọn Júù. Lẹ́yìn náà, wọ́n so Jésù, wọn sì múu lọ. Wọ́n fi lé Pílátù lọ́wó. \v 2 Pílátù biì, "Sé ìwọ ni ọba àwọn Júù?" Ó dáalóhùn, "Ìwọ́ wí." \v 3 Àwọn olórí àlùfáà nfi ẹ̀sùn púpọ̀ kan Jésù.
|
||||
\c 15 \v 1 Ní àárọ̀ kùtùkùtù, àwọn olórí àlúfàà pàdé pẹ̀lú àwọn àgbààgbà pẹ̀lú àwọn akọ̀wé àti gbogbo ìgbìmọ̀ àwọn Júù. Lẹ́yìn náà ni wọ́n so Jésù, wọ́n sì múu lọ. Wọ́n fi lé Pílátù lọ́wó. \v 2 Pílátù bií, "Sé ìwọ ni ọba àwọn Júù bí?" Ó dáalóhùn, "Ìwọ́ wí." \v 3 Àwọn olórí àlùfáà nfi ẹ̀sùn púpọ̀ kan Jésù.
|
Loading…
Reference in New Issue