Thu May 16 2019 12:25:34 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-05-16 12:25:35 +01:00
parent 96114c31bc
commit 483af147ee
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 17 Ẹnìkan láàrín èrò sì dáhùn ó wípé, "Olùkó, mo mú ọmọ mi tọ̀ Ọ́ wá.Ẹ̀míkẹ́mìí kan ti jẹ́ kó ya odi \v 18 Ó má ń gbáa mú, á sì gbée sánlẹ̀, bẹ́ẹ̀ni ó má ń mú kí ó máa pòfóló, kí ó sì ma payín keke, òun á sì gan pa. Mo bẹ àwọn ọmọ ẹ̀yìn Rẹ kí wọ́n leèle jáde sùgbọ́n wọn kò lee sé." \v 19 Ó sì wí fun wọn pé, "Ìran aláìgbàgbọ́, èmi ó ti bá n yín gbé pẹ́ tó? Èmi ó ti mún sùúrù pẹ́ tó fún n yín? Mú n wá fún mi.?"
\v 17 Ẹnìkan láàrín èrò sì dáhùn ó wípé, "Olùkó, mo mú ọmọ mi tọ̀ Ọ́ wá.Ẹ̀míkẹ́mìí kan ti jẹ́ kó ya odi \v 18 Ó má ń gbáa mú, á sì gbée sánlẹ̀, bẹ́ẹ̀ni ó má ń mú kí ó máa pòfóló, kí ó sì ma payín keke, òun á sì gan pa. Mo bẹ àwọn ọmọ ẹ̀yìn Rẹ kí wọ́n leèle jáde kúrò nínú rẹ̀ sùgbọ́n wọn kò leè ṣeé." \v 19 Ó sì wí fun wọn pé, "Ìran aláìgbàgbọ́, èmi ó ti bá n yín gbé pẹ́ tó? Èmi ó ti mú sùúrù pẹ́ tó fún n yín? Mú u wá fún mi.?"