Fri May 17 2019 08:39:20 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-05-17 08:39:20 +01:00
parent 81401ad14c
commit 47af2c2f1e
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 24 Ṣùgbọ́n lẹ́yìn ìpọ́njú àwọn ọjọ́ náà, oòrùn yio ṣóòkùn, òṣùpá kì yíò tan ìmọ́lẹ̀ rẹ̀, \v 25 àwọn ìrawọ̀ yio jábọ́ lati òkè, àti àwọn agbára ti o wà lọ́run yíó mì. \v 26 Nígbànáà ni nwọ́n o rí Ọmọ Ènìyàn tí ó ǹsọ̀kalẹ̀ láti inú àwọọ́sánmọ̀n pèlú agbára àti ògo. \v 27 Nígbànáà ni yíò ràń àwọn ángẹ́lì rẹ̀, yio si ko àwọn àyànfẹ́ rẹ lati inú orígun mẹ́rin, láti òpin ayé títí dé òpin àwọọ́sánmọ̀n.
\v 24 Ṣùgbọ́n lẹ́yìn ìpọ́njú àwọn ọjọ́ náà, oòrùn yio ṣóòkùn, òṣùpá kì yíò tan ìmọ́lẹ̀ rẹ̀, \v 25 àwọn ìrawọ̀ yio jábọ́ lati òkè, àti àwọn agbára ti o wà lọ́run yíó mì. \v 26 Nígbànáà ni nwọ́n o rí Ọmọ Ènìyàn tí ó ǹsọ̀kalẹ̀ láti inú àwọọ́sánmọ̀n pèlú agbára àti ògo. \v 27 Nígbànáà ni yíò ràń àwọn ángẹ́lì rẹ̀, yio si ko àwọn àyànfẹ́ rẹ lati inú orígun mẹ́rẹ̀rin, láti òpin ayé títí dé òpin àwọọ́sánmọ̀n.