Thu May 20 2021 15:04:13 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
aanuoluwapoadegoke 2021-05-20 15:04:13 +01:00
parent b545aa03e7
commit 45fa1a3bc1
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 26 Ṣùgbọ́n nípa àjíǹde tó ti kú, ẹ̀yin kò ì tí ka nínú ìwé Mose, àkọsílẹ̀ pápá tí ń jó, bí Ọlọ́run se bá Móse pé, Èmi ni Ọlọ́run Abrahamu, Ọlọ́run Isaaki àti Ọlọ́run Jakọbu. 27Òun kì í ṣe Ọlọ́run àwọn òkú bí kò ṣe Ọlọ́run àwọn alààyè: nítorí ẹ̀yin ṣe àṣìṣe gidigidi.”\v 27 dd
\v 26 Ṣùgbọ́n nípa àjíǹde tó ti kú, ẹ̀yin kò ì tí ka nínú ìwé Mósè, àkọsílẹ̀ pápá tí ń jó, bí Ọlọ́run se bá Mósè sọ̀rọ̀ tó wípé, Èmi ni Ọlọ́run Ábráhámù, Ọlọ́run Ísáákì àti Ọlọ́run Jákọ́bù? \v 27 Òun kì í ṣe Ọlọ́run àwọn òkú, bí kò ṣe Ọlọ́run àwọn alààyè. nítorí ẹ̀yin ṣe àṣìṣe gidigidi.”