Wed May 26 2021 12:23:44 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)
This commit is contained in:
parent
42ef1af708
commit
450608ea27
|
@ -1 +1 @@
|
|||
\c 12 \v 1 Nígbà náà ni Jésù bẹ̀rẹ̀ sí í fi òwe kọ́ wọn. Ó wípe, “Ọkùnrin kan gbin ọgbà àjàrà kan, Ó ṣe ọgbà yìí ká, ó sì wá ilẹ̀ fún ìfúntí wáìnì. Ó kọ́ ilé ìṣọ́, ó sì fi ṣe àgbàtọ́jú fún àwọn olùṣọ́gbà. Ó sì lọ sí ìrìnàjò. \v 2 Lákokò tí ó tọ́, ọkùnrin náà rán ọ̀kan nínú àwọn ọmọ ọ̀dọ̀ rẹ̀ sí àwọn olùṣọ́gbà náà, kí ó gbà nínú èso ọgbà àjàrà náà lọ́wọ́ àwọn olùṣọ́gbà. \v 3 Ṣùgbọ́n wọ́n mú u, wọ̀n lù ú, wọ́n sì rán an padà lọ́wọ́ òfo.
|
||||
\c 12 \v 1 Nígbànáà ni Jésù bẹ̀rẹ̀ sí í fi òwe kọ́ wọn. Ó wípe, “Ọkùnrin kan gbin ọgbà àjàrà kan, Ó ṣe ọgbà yìí ká, ó sì wá ilẹ̀ fún ìfúntí wáìnì. Ó kọ́ ilé ìṣọ́, ó sì fi ṣe àgbàtọ́jú fún àwọn olùṣọ́gbà. Ó sì lọ sí ìrìnàjò. \v 2 Lákokò tí ó tọ́, ọkùnrin náà rán ọ̀kan nínú àwọn ọmọ ọ̀dọ̀ rẹ̀ sí àwọn olùṣọ́gbà náà, kí ó gbà nínú èso ọgbà àjàrà náà lọ́wọ́ àwọn olùṣọ́gbà. \v 3 Ṣùgbọ́n wọ́n mú u, wọ̀n lù ú, wọ́n sì rán an padà lọ́wọ́ òfo.
|
|
@ -91,7 +91,6 @@
|
|||
"08-35",
|
||||
"08-38",
|
||||
"12-title",
|
||||
"12-01",
|
||||
"12-04",
|
||||
"12-06",
|
||||
"12-08",
|
||||
|
|
Loading…
Reference in New Issue