diff --git a/04/21.txt b/04/21.txt index fece3f8..c62404c 100644 --- a/04/21.txt +++ b/04/21.txt @@ -1 +1 @@ -\v 21 Jésù wí fún wọn pé, “A ha lè gbé fìtílà wọ inú ilé láti fi sábẹ́ agbọ̀n tàbí sábẹ́ àkéte? a o gbé e ka orí ọ̀pá fìtílà ni. 23Bí ẹnikẹ́ni bá ní etí láti fi gbọ́, kí ó gbọ́.” \v 22 Nítorí kò sí ohun tí ó pamọ́ tì hàn ní gbangba ní ọjọ́ kan, bẹ́ẹ̀ ni kò sí ohun tí ó wà ní ìkọ̀kọ̀, bí kò ṣe pé kí ó le yọ sí gbangba. \v 23 dd \ No newline at end of file +\v 21 Jésù wí fún wọn pé, “A ha lè gbé fìtílà wọ inú ilé láti fi sábẹ́ agbọ̀n tàbí sábẹ́ àkéte? a o gbé e ka orí ọ̀pá fìtílà ni. \v 22 Nítorí kò sí ohun tí ó pamọ́ tí a kò ní fihàn, bẹ́ẹ̀ ni kò sí ohun tí ó wà ní ìkọ̀kọ̀, tí kò ní wá sí gbangba. \v 23 Bí ẹnikẹ́ni bá ní etí láti fi gbọ́, kí ó gbọ́!” \ No newline at end of file diff --git a/manifest.json b/manifest.json index eff1a25..4db2849 100644 --- a/manifest.json +++ b/manifest.json @@ -64,6 +64,7 @@ "04-10", "04-13", "04-16", - "04-18" + "04-18", + "04-21" ] } \ No newline at end of file