Fri May 17 2019 08:07:20 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-05-17 08:07:20 +01:00
parent 5dfeaf4fd2
commit 409649d040
3 changed files with 3 additions and 3 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 5 Jésù sí bẹ̀rẹ̀ síí sọ́ fun wọn pé, "Ẹ kíyèsára kí ẹnikẹ́ni máṣe ṣì yiń lọ́nà. \v 6 Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ni yóó wàá ní orúkọ mì tí wọ́n yíò sọ pé, 'Èmi ni ẹní nà,' nwọ́n ó sì ṣi ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn lọ́nà.
\v 5 Jésù sí bẹ̀rẹ̀ síí sọ́ fun wọn pé, "Ẹ kíyèsára kí ẹnikẹ́ni máṣe ṣì yiń lọ́nà. \v 6 Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ni yóó wàá lórúkọ mì, tí wọ́n yíò sọ pé, 'Èmi ni ẹní nà,' nwọ́n yóò sì ṣi ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn lọ́nà.

View File

@ -1 +1 @@
\v 7 Nígbàtí ẹ̀yin bá ń gbọ́ ìró ogun tàbí àwọn ọ̀rọ̀ nípa ogun, ẹ máṣe ṣe àníyàn; àwọn ǹkan wọ̀nyí gbọdọ̀ ṣẹlẹ̀, ṣùgbọ́n òpin kò ì tí dè. \v 8 Nítorí orílẹ̀èdè yíò dìde sí ara wọn, àti ìjọba lòdì sí ìjọba. Ilẹ̀ ríru yíó wà ní ọpọ̀lọpọ̀ ibi, àti ìyaǹ. Ǹwọ̀nyí ni ìbẹ̀rẹ̀ ìbí ìnira.
\v 7 Nígbàtí ẹ̀yin bá ń gbọ́ ìró ogun tàbí àwọn ọìrọ̀ nípa ogun, ẹ máṣe ṣe àníyàn; àwọn ǹkan wọ̀nyí gbọdọ̀ ṣẹlẹ̀, ṣùgbọ́n òpin kò ì tí dè. \v 8 Nítorí orílẹ̀èdè yíò dìde sí ara wọn, àti ìjọba lòdì sí ìjọba. Ilẹ̀ ríru yíó wà ní ọpọ̀lọpọ̀ ibi, àti ìyaǹ. Ǹwọ̀nyí ni ìbẹ̀rẹ̀ ìbí ìnira.

View File

@ -38,7 +38,7 @@
"finished_chunks": [
"13-title",
"13-01",
"13-07",
"13-05",
"13-09",
"13-11",
"13-14",