Thu May 16 2019 15:33:18 GMT-0900 (Alaskan Standard Time)
This commit is contained in:
parent
3059bd4782
commit
3b52b2ccb5
|
@ -1 +1 @@
|
|||
\v 38 Jésù dá wọn lóhùn, ẹ kò mọ ohun tí ẹ̀yin ńbèrè. Ẹ̀ yín a le mu ife tí èmi yóò mu tàbí farada ìtẹ̀bọmi tí a ó fi rì mí bọmi?" \v 39 Wọ́n wí fún pé, "àwa leè sé" Jésù wí fún wọn pé , ife tí èmi yóò mu ni ẹ̀yin náà yóò mu àti ìtẹ̀bọmi tí èmi ó se ni aó se fún ẹ̀yin náà. \v 40 Sùgbọ́n, ẹni tí yóò jókòó ní ọwọ́ ọ̀tún mi àti ní ọwọ́ òsì mi, kìí se tèmi láti fúnni bíkòse àwọn tí a ti pèsèe rẹ̀ sílẹ̀ fún."
|
||||
\v 38 Jésù dá wọn lóhùn, ẹ kò mọ ohun tí ẹ̀yin ńbèrè. Ẹ̀ yín a le mu ife tí èmi yóò mu tàbí farada ìtẹ̀bọmi tí a ó fi rì mí bọmi?" \v 39 Wọ́n wí fún pé, "àwa leè sé" Jésù wí fún wọn pé , ife tí èmi yóò mu ni ẹ̀yin náà yóò mu àti ìtẹ̀bọmi tí èmi ó se ni aó se fún ẹ̀yin náà. \v 40 Ṣùgbọ́n, ẹni tí yóò jókòó ní ọwọ́ ọ̀tún mi àti ní ọwọ́ òsì mi, kìí se tèmi láti fúnni bíkòse àwọn tí a ti pèsèe rẹ̀ sílẹ̀ fún."
|
Loading…
Reference in New Issue