From 396031fea99af3df35666be35cb6327092d11189 Mon Sep 17 00:00:00 2001 From: aanuoluwapoadegoke Date: Thu, 20 May 2021 13:46:13 +0100 Subject: [PATCH] Thu May 20 2021 13:46:12 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time) --- 08/33.txt | 4 +--- 1 file changed, 1 insertion(+), 3 deletions(-) diff --git a/08/33.txt b/08/33.txt index 7195440..3e493a6 100644 --- a/08/33.txt +++ b/08/33.txt @@ -1,3 +1 @@ -\v 33 Ṣùgbọ́n Jesu yípadà, ó wo àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀. Ó sì dá Peteru lẹ́kun, “Kúrò lẹ́yìn mi, Satani! Iwọ kò ro ohun tí Ọlọ́run bí kò ṣe ohun tí ènìyàn.” -Ọ̀nà sí àgbélébùú -34 Nígbà náà ni Jesu pe àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ àti ọ̀pọ̀ ènìyàn láti bá wọn sọ̀rọ̀, ó wí fún wọn pé, “Bí ẹnikẹ́ni bá fẹ́ tọ̀ mí lẹ́yìn, kí ó sẹ́ ara rẹ̀, kí ó si gbé àgbélébùú rẹ̀, kí ó si máa tọ̀ mi lẹ́yìn.\v 34 dd \ No newline at end of file +\v 33 Ṣùgbọ́n Jesu yípadà, ó wo àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀. Ó sì dá Peteru lẹ́kun, “Kúrò lẹ́yìn mi, Satani! Ìwọ kò ro ohun tí Ọlọ́run bí kò ṣe ohun tí ènìyàn.” \v 34 Nígbà náà ni Jesu pe àwọn ọ̀pọ̀ ènìyàn àti àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ jọ, ó wí fún wọn pé, “Bí ẹnikẹ́ni bá fẹ́ tọ̀ mí lẹ́yìn, ó gbọ́dọ̀ sẹ́ ara rẹ̀, kí ó gbé àgbélébùú rẹ̀, kí ó si máa tọ̀ mi lẹ́yìn. \ No newline at end of file