Thu May 16 2019 12:37:34 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-05-16 12:37:35 +01:00
parent 3f76fc8f59
commit 36667f6164
2 changed files with 2 additions and 2 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 23 Jésù wí fún pé, "Bí ìwọ bá nípá? Ohun gbogbo ni ṣíṣe fún àwọn tí ó gbàgbọ́." \v 24 Lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, bàbá ọmọ náà kígbe sókè wípé, "Mo gbàgbọ́! Ran àìgbàgbọ́ mi lọ́wọ´." \v 25 Nígbàtí Jésù rí ọ̀pọ̀ èrò tó n wá sọ́dọ̀ rẹ̀, Ó bá ẹ̀mí àìmọ́ náà wí, ó wípé, "Ìwọ ẹ̀mí odi àti ìdití, mo pàṣẹ fún o, jáde kúrò lára rẹ̀ kí o má sìse padà síbẹ̀ mọ́."
\v 23 Jésù wí fún pé, "Bí ìwọ bá nípá? Ohun gbogbo ni ṣíṣe fún àwọn tí ó gbàgbọ́." \v 24 Lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, bàbá ọmọ náà kígbe sókè wípé, "Mo gbàgbọ́! Ran àìgbàgbọ́ mi lọ́wọ´." \v 25 Nígbàtí Jésù rí ọ̀pọ̀ èrò tó n wá sọ́dọ̀ rẹ̀, Ó bá ẹ̀mí àìmọ́ náà wí, ó wípé, "Ìwọ ẹ̀mí odi àti ìdití, mo pàṣẹ fún ọ, jáde kúrò lára rẹ̀ kí o má sì ṣe padà síbẹ̀ mọ́."

View File

@ -1 +1 @@
\v 26 /\v 26 Ó kígbe sókè kíkan, Ó gbé ọmọkùnrin náà janlẹ̀ gidigidi, ósì jáde kúrò lára rẹ̀. Ọmọkùnrin náà wò bíi ẹnití ó ti kú, tóbẹ̀ẹ̀ tí àwọn ènìyàn fi wí pé, "ó ti kú". \v 27 Sùgbọ́n Jésù gbá ọwọ́ ọmọ náà mún, Ó fàá sókè, ọmọ náà sì dìd dúró.
\v 26Ó kígbe stòò ó si n, Ó gbé ọmọkùnrin náà janlẹ̀ gidigidi, ósì jáde kúrò lára rẹ̀. Ọmọkùnrin náà wò bíi ẹnití ó ti kú, tóbẹ̀ẹ̀ tí àwọn ènìyàn fi wí pé, "ó ti kú". \v 27 Sùgbọ́n Jésù gbá ọwọ́ ọmọ náà mún, Ó fàá sókè, ọmọ náà sì dìd dúró.