Wed Jun 26 2019 13:46:57 GMT-1200 (Dateline Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-06-26 13:46:58 -12:00
parent ac1627f545
commit 2d21904d6d
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 5 Ní gbogbo ọ̀sán àti òru ni isà-òkú ati ní àwọn orí-òkè, Ó ma ń pariwo jáde Ó si ma tún gé ara rẹ̀ lára pẹ̀lú àwon òkúta tí ó mú. \v 6 Nígbàtí ó rí Jésù láti jìnnàjìnnà, ó sáré si, o sì wólẹ̀ níwájú rẹ̀.
\v 5 Ní gbogbo ọ̀sán àti òru ni isà-òkú àti ní àwọn orí-òkè, Ó ma ń pariwo jáde Ó si ma tún ya ara rẹ̀ lára pẹ̀lú àwon òkúta tí ó mú. \v 6 Nígbàtí ó rí Jésù láti jìnnàjìnnà, ó sáré si, o sì wólẹ̀ níwájú rẹ̀.