Thu Jun 27 2019 11:19:09 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-06-27 11:19:11 +01:00
parent 20d936b328
commit 2cdcc43a7d
2 changed files with 2 additions and 2 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 42 Nígbàtí alẹ́ dé, nítorípé ó jẹ́ ọjọ́ ìpalẹ̀mọ́ fún Sábátì \v 43 Jósẹ́fù ará Arimatia wá síbẹ̀. Ó jẹ́ ènìyàn pàtàkì nínú ìgbìmọ̀ tó ń dúró de ìjọba Ọlọ́run. Ólọ sí ọ̀dọ Pílátù pẹ̀lù ìgboyà láti bèrè fún ara Jésù. \v 44 Ẹnú ya Pílátù pé Jésù ti kú; ó pe ògágun-ọgọ̀rún láti bií bóyá Jésù ti kú.
\v 42 Nígbàtí alẹ́ dé, nítorípé ó jẹ́ ọjọ́ ìpalẹ̀mọ́ fún Sábátì \v 43 Jósẹ́fù ará Arimatia wá síbẹ̀. Ó jẹ́ ènìyàn pàtàkì nínú ìgbìmọ̀ tó ń dúró de ìjọba Ọlọ́run. Ó lọ sí ọ̀dọ Pílátù pẹ̀lù ìgboyà láti bèrè fún ara Jésù. \v 44 Ẹnú ya Pílátù pé Jésù ti kú; ó pe ògágun-ọgọ̀rún láti bií bóyá Jésù ti kú.

View File

@ -1 +1 @@
\v 45 Nígbàtí Pílátù gbọ́ láti ọ̀dọ ọ̀gágun-ọgọ̀rún pé Jésù ti kú, ó yọ̀ǹda ara rẹ̀ fún Jósẹ́fù \v 46 Jóséfù sì ti ra asọ dídán kan. Ó gbe sọ̀kalẹ̀ láti orí àgbélèbú, ó fi asọ náà wée, ó sì tẹ sí inú ibojì tí a ti gbẹ́ nínú àpáta. Nígbànáà, ó yí òkúta sí ẹnu ọ̀nà ibojì náà \v 47 Maria Magdaleni àti Maria ìya Jósè sì rí ibi tí a sin Jésù sí.
\v 45 Nígbàtí Pílátù gbọ́ láti ọ̀dọ ọ̀gágun-ọgọ̀rún pé Jésù ti kú, ó yọ̀ǹda ara rẹ̀ fún Jósẹ́fù \v 46 Jóséfù sì ti ra asọ dídán kan. Ó gbe sọ̀kalẹ̀ láti orí àgbélèbú, ó fi asọ náà wée, ó sì tẹ sí inú ibojì tí a ti gbẹ́ nínú àpáta. Nígbà náà, ó yí òkúta sí ẹnu ọ̀nà ibojì náà \v 47 Maria Magdaleni àti Maria ìya Jósè sì rí ibi tí a sin Jésù sí.