Thu Jun 27 2019 11:15:09 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-06-27 11:15:11 +01:00
parent 877da47f1f
commit 2c37f85bed
4 changed files with 4 additions and 4 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 22 Àwọn ọmọ ogun náà mú Jésù lọ sí ibi tí à ńpè ní Gọ́lgọ́tà (èyí tí ìtumọ̀ rẹ̀ ńjẹ́, "Ibi agbárí"). \v 23 Wọ́n fun ní wáínì tí a pò pẹ̀lú òjìá, ùgbọ́n kò muú \v 24 Wón Kàn-án mọ́ àgbélèbú nígbàtí wọ́n sì sẹ́ gègé láti pín asọ rẹ̀ láàrin ara wọn.
\v 22 Àwọn ọmọ ogun náà mú Jésù lọ sí ibi tí à ńpè ní Gọ́lgọ́tà (èyí tí ìtumọ̀ rẹ̀ ńjẹ́, "Ibi agbárí"). \v 23 Wọ́n fun ní wáínì tí a pò pẹ̀lú òjìá, ùgbọ́n kò muú \v 24 Wón Kàn-án mọ́ àgbélèbú nígbàtí wọ́n sì sẹ́ gègé láti pín asọ rẹ̀ láàrin ara wọn.

View File

@ -1 +1 @@
\v 25 Ójẹ́ wákàtí kẹẹ̀ta ọjọ́ nigbàtí wọ́n kàán mọ́ àgbélèbú \v 26 Wọ́n kọ ẹ̀sùn rẹ̀ sí orí pátákó kan pé, "Ọba àwọn júù." \v 27 Wọ̀n kàn-án mọ́ àgbélèbú pẹ̀lú olè mèjí, ìkan ní ọwọ́ ọ̀tún àti ìkan ní ọwọ́ òsì \v 28 "Amú ìwé mímọ́ náà ṣẹ pé, 'Akàá pẹ̀lú àwọn arúfin.'
\v 25 Ójẹ́ wákàtí kẹẹ̀ta ọjọ́ nigbàtí wọ́n kà-án mọ́ àgbélèbú \v 26 Wọ́n kọ ẹ̀sùn rẹ̀ sí orí pátákó kan pé, "Ọba àwọn júù." \v 27 Wọ̀n kàn-án mọ́ àgbélèbú pẹ̀lú olè mèjí, ìkan ní ọwọ́ ọ̀tún àti ìkan ní ọwọ́ òsì \v 28 "Amú ìwé mímọ́ náà ṣẹ pé, 'Akàá pẹ̀lú àwọn arúfin.'

View File

@ -1 +1 @@
\v 31 Bàkanáà ni àwọn olórí àlàfáà ńse ẹlẹ́yà rẹ̀ láàrín ara wọn, pẹ̀lú àwọn akọ̀wé, wọ́n sì wípé, "Ó gba àwọn míràn là sùgbọ́n kò lè gba ara rẹ̀. \v 32 Jẹ́kí Krístì náà, Ọba Ísrẹ́ẹ́lì náà, sọ̀kalẹ̀ nísisìyí láti orí àgbélèbú, kí àwá lè ríi, kí à sì gbàgbọ́," àwọn tí a kàn mọ́ àgbélèbú pẹ̀lú rẹ̀ náà sì kẹ́gàn rẹ̀.
\v 31 Bàkanáà ni àwọn olórí àlàfáà ńse ẹlẹ́yà rẹ̀ láàrín ara wọn, pẹ̀lú àwọn akọ̀wé, wọ́n sì wípé, "Ó gba àwọn míràn là sùgbọ́n kò lè gba ara rẹ̀. \v 32 Jẹ́kí Krístì náà, Ọba Ísrẹ́ẹ́lì náà, sọ̀kalẹ̀ nísinnyí láti orí àgbélèbú, kí àwá lè ríi, kí à sì gbàgbọ́," àwọn tí a kàn mọ́ àgbélèbú pẹ̀lú rẹ̀ náà sì kẹ́gàn rẹ̀.

View File

@ -45,9 +45,9 @@
"15-14",
"15-16",
"15-19",
"15-22",
"15-25",
"15-29",
"15-31",
"15-33",
"15-36",
"15-39",