Tue May 14 2019 15:02:34 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-05-14 15:02:35 +01:00
parent 9ac42f14e7
commit 1733c7a5df
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 33 Lẹ́hìn náà ni wọ́n wá sí Kápánámù. Nígbàtí ó sì ti wọ sínú ilé kan, Ó biwọ́n léèrè pé, "Kíni ẹ̀yin n bára yín sọ lójú ọ̀nà.?" \v 34 Wọ́n sì dákẹ́ jẹ́ẹ́. Nítorítí wọ́n ti n se àríyànjiyàn láàrin ara wọn níti ẹnití ó pọ̀jùlọ láàrin wọn. \v 35 Nígbàtí Ó Jókòó, Ó pe àwọn méjìlá sí ọ̀dọ̀ ara rẹ̀ ós wi fun won pe, "bi enikeni bafe se eni akoko, Oun ni yio je eni ikeyin ati iranse gbogbo eniyan."
\v 33 Lẹ́hìn náà ni wọ́n wá sí Kápánámù. Nígbàtí ó sì ti wọ sínú ilé kan, Ó biwọ́n léèrè pé, "Kíni ẹ̀yin n bára yín sọ lójú ọ̀nà.?" \v 34 Wọ́n sì dákẹ́ jẹ́ẹ́. Nítorítí wọ́n ti n se àríyànjiyàn láàrin ara wọn níti ẹnití ó pọ̀jùlọ láàrin wọn. \v 35 Nígbàtí Ó Jókòó, Ó pe àwọn méjìlá sí ọ̀dọ̀ ara rẹ̀ ósì wí fún wọn pé, "bí ẹnikẹ́ni bá fẹ́ se ẹni àkọ́kọ́, Oun ni yíò jẹ́ ẹni ikeyin ati iranse gbogbo eniyan."