Tue Feb 27 2018 12:37:58 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2018-02-27 12:37:58 +01:00
parent 48906afe3e
commit 135addd363
3 changed files with 4 additions and 3 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 18 Nitori Johanu ba Herodu wi, "pe ko tona lati yan aya arakunrin re lale." \v 19 Herodia si binu si Johanu, o si n wa ona lati pa a, eyi si nira fun \v 20 nitori Herodu beru Johanu. Ati wipe o mo pe olododo ati eniyan mimo ni, o si pa a mo. Gbigbo oro ma n bii ninu, sugbon o ma n fi ayo gboo.
\v 18 Nitori Johanu ba Herodu wi, "pe ko tona lati yan aya arakunrin re lale." \v 19 Herodia si binu si Johanu, o si n wa ona lati pa a, eyi si nira fun \v 20 nitori Herodu beru Johanu. Ati wipe o mo pe olododo ati eniyan mimo ni, o si pa a mo. Gbigbo oro re ma n bii ninu, sugbon o ma n fi ayo gboo.

View File

@ -1 +1 @@
\v 21 \v 22 Anfani lati pa Johanu wa nigbati Oba Herodu se ase ojo ibi fun awon emewa re ati awon adari ni ile Galili. Omobirin Herodia si wa fi ijo da Herudo ati awon alejo re laraya. Oba Herodu si wipe fun omo na pe: bere ohnu ti o ba fe ni owo mi, emi o si fi fun o?
\v 21 Anfani lati pa Johanu wa nigbati Oba Herodu se ase ojo ibi fun awon emewa re ati awon adari ni ile Galili. \v 22 Omobirin Herodia si wa fi ijo da Herudo ati awon alejo re laraya. Oba Herodu si wipe fun omo na pe: bere ohnu ti o ba fe ni owo mi, emi o si fi fun o?

View File

@ -42,6 +42,7 @@
"06-10",
"06-12",
"06-14",
"06-16"
"06-16",
"06-18"
]
}