Tue May 18 2021 21:34:39 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
aanuoluwapoadegoke 2021-05-18 21:34:39 +01:00
parent f18e29eb63
commit 119e068486
3 changed files with 5 additions and 2 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 30 Ó sì tún wí pé, “Kí ni a ò bá fi ìjọba Ọlọ́run wé, tàbí òwe wo ni a lè fi ṣe àkàwé rẹ̀? \v 31 Ó dàbí èso hóró musitadi, nígbàt ó jọ ọ̀kan nínú àwọn èso tí ó kéré jùlọ ti a gbìn sínú ilẹ̀. \v 32 Síbẹ̀, nígbà tí a gbìn ín, ó dàgbàsókè, ó gbilẹ̀, ó sì di títóbi ju gbogbo ewéko inú ọgbà yòókù lọ, ó sì yọ ẹ̀ka ńlá, tóbẹ̀ tí àwọn ẹyẹ ọ̀run lè kọ́ ìtẹ́ wọn sí ìbòji rẹ kí wọn sì rí ìdáàbòbò.”
\v 30 Ó sì tún wí pé, “Kí ni a ò bá fi ìjọba Ọlọ́run wé, tàbí òwe wo ni a lè fi ṣe àkàwé rẹ̀? \v 31 Ó dàbí èso hóró musitadi, nígbàt ó jọ ọ̀kan nínú àwọn èso tí ó kéré jùlọ ti a gbìn sínú ilẹ̀. \v 32 Síbẹ̀, nígbà tí a gbìn ín, ó dàgbàsókè, ó gbilẹ̀, ó sì di títóbi ju gbogbo ewéko inú ọgbà yòókù lọ, ó sì yọ ẹ̀ka ńlá, tóbẹ̀ tí àwọn ẹyẹ ọ̀run lè kọ́ ìtẹ́ wọn sí ìbòji rẹ̀.

2
04/33.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1,2 @@
\v 33 Òun lo ọ̀pọ̀ irú òwe wọ̀nyí láti ba àwọn ènìyàn sọrọ̀, gẹ́gẹ́ bí wọ́n bá ti ní òye tó, \v 34 Kìkì òwe ni Jesu fi ń kọ́ àwọn ènìyàn ní ẹ̀kọ́ ìta gbangba rẹ̀. Ṣùgbọ́n lẹ́yìn èyí, nígbà tí ó bá sì wà pẹ̀lú àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀, òun a sì sọ ìtumọ̀ ohun gbogbo.
Jesu mú afẹ́fẹ́ okun dákẹ́ jẹ́ẹ́

View File

@ -67,6 +67,7 @@
"04-18",
"04-21",
"04-24",
"04-26"
"04-26",
"04-30"
]
}