Mon May 13 2019 14:52:22 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-05-13 14:52:23 +01:00
parent 5b64fb9fe1
commit 0b9e667fda
3 changed files with 2 additions and 3 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 8 Loju ese Jesu mo ohun ti won nro larin ara won ninu okan re. O wi fun won, "Ese ti eyi fi nro eyi ninu okan yin?" \v 9 Ewo ni o rorun ju lati wi fun okunrin ti o ro na, 'A fi gbogbo ese re jin o' tabi lati wipe 'Dide, gbe ibusun re ki o si ma rin?'
\v 8 Loju ese Jesu mo ohun ti won nro larin ara won ninu okan re. O wi fun won, "Ese ti eyi fi nro eyi ninu okan yin?" \v 9 Ewo ni o rorun ju lati wi fun okunrin ti o ro na, 'A dari gbogbo ese re jin o' tabi lati wipe 'Dide, gbe ibusun re ki o si ma rin?'

View File

@ -1 +1 @@
\v 10 Sugbon ki eyin ki o le mo wipe Omo eniyan ni ase ni aiye lati fi ese jin" O wi fun alaida ara na, \v 11 "mo wi fun o, dide, gbe eni re, ki o si ma lo si ile re." \v 12 O dide loju ese o si gbe eni re, o si jade kuro ninu ile na loju gbogbo eniyan, tobe ti enu si ya gbogbo won ti won si fi ogo fun Olorun, won si wipe,"A ko ti ri iru eleyi ri."
\v 10 Sugbon ki eyin ki o le mo wipe Omo eniyan ni ase ni aiye lati dari ese jin" O wi fun ti o ro naa, \v 11 "mo wi fun o, dide, gbe eni re, ki o si ma lo si ile re." \v 12 O dide loju ese o si gbe eni re, o si jade kuro ninu ile na loju gbogbo eniyan, tobe ti enu si ya gbogbo won ti won si fi ogo fun Olorun, won si wipe,"A ko ti ri iru eleyi ri."

View File

@ -37,7 +37,6 @@
],
"finished_chunks": [
"02-01",
"02-10",
"02-13",
"02-15",
"02-17",