diff --git a/06/18.txt b/06/18.txt index fdc624e..0080ba6 100644 --- a/06/18.txt +++ b/06/18.txt @@ -1 +1 @@ -\v 18 Nítorí Jòhánù bá Hẹ́rọ́dù wí, "pé kò tọ̀nà láti yan aya arákùnrin rẹ̀ lálè." \v 19 Hẹrọdíà sì bínú sí Jòhánù, ó sì ń wá ọ̀nà láti pa a, eyi si nira fun \v 20 nitori Herodu beru Johanu. Ati wipe o mo pe olododo ati eniyan mimo ni, o si pa a mo. Gbigbo oro re ma n bii ninu, sugbon o ma n fi ayo gboo. \ No newline at end of file +\v 18 Nítorí Jòhánù bá Hẹ́rọ́dù wí, "pé kò tọ̀nà láti yan aya arákùnrin rẹ̀ lálè." \v 19 Hẹrọdíà sì bínú sí Jòhánù, ó sì ń wá ọ̀nà láti pa á, èyí sì nira fún \v 20 nítorí Hẹ́rọ̀dù bẹ̀ru Jòhánù. Àti wípé ó mọ̀n pé olódodo àti ènìyn mimo ni, o si pa a mo. Gbigbo oro re ma n bii ninu, sugbon o ma n fi ayo gboo. \ No newline at end of file