Thu May 20 2021 15:00:13 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
aanuoluwapoadegoke 2021-05-20 15:00:13 +01:00
parent 9739ffb03f
commit 0701fa3cf4
3 changed files with 4 additions and 2 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 24 Jesu wí fún wọn pé, “Kì í há ṣe nítorí èyí ni ẹ ṣe ṣìnà, nítorí ẹ̀yin kò mọ ìwé Mímọ́ tàbí agbára Ọlọ́run? \v 25 Nítorí pé, nígbà tí àwọn arákùnrin méje yìí àti obìnrin náà bá jí dìde nínú òkú, a kò ní ṣe ìgbéyàwó fún wọn. Wọn yóò dàbí àwọn angẹli tí ń bẹ ní ọ̀run.
\v 24 Jesu wí fún wọn pé, “Kì í há ṣe nítorí èyí ni ẹ ṣe ṣìnà, nítorí ẹ̀yin kò mọ ìwé Mímọ́ tàbí agbára Ọlọ́run? \v 25 Nítorí pé, nígbà tí wọ́n bá jí dìde nínú òkú, a kò ní ṣe ìgbéyàwó fún wọn, ṣùgbọ́n wọn dàbí àwọn angẹli tí ń bẹ ní ọ̀run.

1
12/26.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 26 Ṣùgbọ́n nísinsin yìí, nípa bóyá àjíǹde yóò wà. Àbí ẹ̀yin kò ì tí ka ìwé Eksodu, nípa Mose àti pápá tí ń jó? Ọlọ́run sọ fún Mose pé, Èmi ni Ọlọ́run Abrahamu, Ọlọ́run Isaaki àti Ọlọ́run Jakọbu. 27Òun kì í ṣe Ọlọ́run àwọn òkú bí kò ṣe Ọlọ́run àwọn alààyè: nítorí ẹ̀yin ṣe àṣìṣe gidigidi.”\v 27 dd

View File

@ -99,6 +99,7 @@
"12-13",
"12-16",
"12-18",
"12-20"
"12-20",
"12-24"
]
}