Mon Nov 25 2019 04:42:37 GMT-0800 (Pacific Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-11-25 04:42:39 -08:00
parent ffa21b0100
commit 04d8232899
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 32 Wón sì wá sí ibi kàn tí à ńpè ní Gẹ́tsímánì, ó sì wí fún àwọn ọmọ èyìn rẹ̀ pé, "Ẹ jókǒ ní hín nígbàtí mo bá lọ gbàdúrà. \v 33 Ó sì mú Peteru àti Jakọbu àti Johanu pẹ̀lú rẹ̀, ó sì bẹré sí ní rẹ̀wẹ̀sì ọkàn rẹ̀ sí dàrú gidigidi. \v 34 Ó sì wí fún wọn pé, "Ọkàn mi ńkãnu gidigidi, títí dé ojú ikú. Ẹ dúró níhǐn kí ẹ sì mã ṣọ́nà.
\v 32 Wón sì wá sí ibi kàn tí à ńpè ní Gẹ́tsímánì, ó sì wí fún àwọn ọmọ èyìn rẹ̀ pé, "Ẹ jókǒ ní ìhín nígbàtí mo bá lọ gbàdúrà. \v 33 Ó sì mú Pétérù àti Jákọ́bù àti Jòhánù pẹ̀lú rẹ̀, ó sì bẹ̀rẹ́ sí ní ìrẹ̀wẹ̀sí ọkàn rẹ̀ sí dàrú gidigidi. \v 34 Ó sì wí fún wọn pé, "Ọkàn mi ńkãnu gidigidi, títí dé ojú ikú. Ẹ dúró níhǐn kí ẹ sì mã ṣọ́nà.