From 0285aaef05dec345fe64bc4a3c40f96bb38a93c7 Mon Sep 17 00:00:00 2001 From: tsDesktop Date: Wed, 15 May 2019 23:51:04 +0100 Subject: [PATCH] Wed May 15 2019 23:51:04 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time) --- 03/20.txt | 2 +- 1 file changed, 1 insertion(+), 1 deletion(-) diff --git a/03/20.txt b/03/20.txt index 0563998..056de7c 100644 --- a/03/20.txt +++ b/03/20.txt @@ -1 +1 @@ -\v 20 Lẹ́yí èyí o lọ́ sí ilé, ọpọ ènìyàn si kojọ lẹẹkan si to bẹ ti wọn kole raye fun oúnjẹ. \v 21 Nigba ti awọn ẹbi rẹ si gbọ nipa ohun ti o n sẹlẹ, wọn jade lati lọ mu nitoriti wọn wipe "ko mọ ohun ti o n se." \v 22 Awọn Akọwe ti o ti Jerusalemu wa wipe, "ẹ̀mí beelsebubu ti gbee wọ" ati wipe "nipa olori awọn ẹ̀mí òkùnkùn ni o le awọn ẹ̀mí òkùnkùn jade." \ No newline at end of file +\v 20 Lẹ́yí èyí o lọ́ sí ilé, ọ̀pọ̀ ènìyàn sì kójọ lẹẹ̀kan si to bẹ ti wọn kole raye fun oúnjẹ. \v 21 Nigba ti awọn ẹbi rẹ si gbọ nipa ohun ti o n sẹlẹ, wọn jade lati lọ mu nitoriti wọn wipe "ko mọ ohun ti o n se." \v 22 Awọn Akọwe ti o ti Jerusalemu wa wipe, "ẹ̀mí beelsebubu ti gbee wọ" ati wipe "nipa olori awọn ẹ̀mí òkùnkùn ni o le awọn ẹ̀mí òkùnkùn jade." \ No newline at end of file