adesinaabegunde_yo_mrk_text.../04/35.txt

1 line
529 B
Plaintext
Raw Normal View History

\v 35 Ní ọjọ́ náà, nígbà tí alẹ́ lẹ́, ó wí fún wọn pé, “Ẹ jẹ́ kí a rékọjá sí apá kejì.” 37Ìjì líle ńlá kan sì dìde, omi sì ń bù sínú ọkọ̀, tó bẹ́ẹ̀ tí ọkọ̀ fi bẹ̀rẹ̀ sí í kún fún omi, ó sì fẹ́rẹ rì. \v 36 Wọ́n fi ọpọ̀ erò sílẹ̀, wọ́n mú Jésù pẹ̀lú wọn, gẹ́gé bí ó ti wà nínú ọkọ̀ ojú omi gẹ́gẹ́ bí ó ti wà. Àwọn ọkọ̀ ojú omi kékeré mìíràn sì wà lọ́dọ̀ rẹ̀. \v 37 ss