Mon Oct 14 2019 10:27:43 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-10-14 10:27:44 +01:00
parent 4d0b7a27b2
commit 812202dc33
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 9 Nísisìyí àwọn tó fẹ́ di ọlọ́rọ̀ ṣubú sínú ìdánwò, sínu pàkúté. Wọ́n ṣubú sínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ òmùgò àti ìfẹ́kúfẹ̌ tí ó ń panilára, àti ohunkóhun tó má ń mú àwọn ènìyàn rì sínú ìparun àti ègbé. \v 10 Nítorí ìfẹ́ owó gbòǹgbò ohun búburù gbogbo. Âwọn ènìyàn tí wọ́ nífẹ̌ rẹ̀ ti ṣìnà kúrò nínu ìgbàgbọ́ wọ́n ti gún ara wọn pèlú ìbìnújé tó pọ̀.
\v 9 Nísisìyí àwọn tó fẹ́ di ọlọ́rọ̀ ṣubú sínú ìdánwò, sínu pàkúté. Wọ́n ṣubú sínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ òmùgò àti ìfẹ́kúfẹ̌ tí ó ń panilára, àti ohunkóhun tó má ń mú àwọn ènìyàn rì sínú ìparun àti ègbé. \v 10 Nítorí ìfẹ́ owó ni gbòǹgbò ohun búburù gbogbo. Âwọn ènìyàn tí wọ́n nífẹ̌ rẹ̀ ti ṣìnà kúrò nínu ìgbàgbọ́ wọ́n ti gún ara wọn pèlú ìbìnújé tó pọ̀.